Scholarship Awards
King James Oladipo Buremoh hands out scholarships to lucky and deserving individuals in Idera, as part of the Ladi Tiger Rural Development Foundation program.
Newsline on Onidera
Article about the progress of the rural development foundation being organized by Kabiyesi James Oladipo Buremoh in the Idera Kingdom.
Oṣù mẹ́fà nínú ọdún ni mo fi ń ṣiṣẹ́ l’Amẹrika, owó rẹ̀ ni mo fi ń tún ìlú ṣe Onidera
Onidera ti ilu Idera, Ọba James Oladipo Buremoh ti ṣalaye bo ṣe maa n lo oṣu mẹfa nilẹ Amẹrika ti yoo si pada wa fi owo to ba pa lọhun tun ilu to jọba le lori ṣe.
Ninu ifọrọwerọ pẹlu BBC Yoruba ni Onidera, to ti fi akoko igba kan jẹ onijakadi lọpọ ọdun sẹyin ṣalaye ọrọ naa.
Irawọ Onidera tan kaakiri gbogbo agbaye lọdun 1987 lasiko to gba ade ijakadi lẹyin to na akẹgbẹ rẹ Mike Hayes lori papa.